Add parallel Print Page Options

Pẹ̀lú ìmọ̀ràn láti ọ̀dọ̀ ìyá rẹ̀, ó béèrè pé, “Fún mi ni orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú àwopọ̀kọ́”. Inú ọba bàjẹ́ gidigidi, ṣùgbọ́n nítorí ìbúra rẹ̀ àti kí ojú má ba à tì í níwájú àwọn àlejò tó wà ba jẹ àsè, ó pàṣẹ pé kí wọ́n fún un gẹ́gẹ́ bí o ti fẹ́. 10 Nítorí náà, a bẹ́ orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú ilé túbú.

Read full chapter

So she, having been prompted by her mother, said, “Give me John the Baptist’s head here on a platter.”

And the king was sorry; nevertheless, because of the oaths and because of those who sat with him, he commanded it to be given to her. 10 So he sent and had John beheaded in prison.

Read full chapter