Font Size
Matiu 8:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 8:2
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 (A)(B)Sì wò ó, adẹ́tẹ̀ kan wà, ó wá ó sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀ ó wí pé, “Olúwa, bí ìwọ bá fẹ́, ìwọ lè sọ mi di mímọ́.”
Read full chapter
Matiu 18:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 18:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
26 (A)“Nígbà náà ni ọmọ ọ̀dọ̀ náà wólẹ̀ lórí eékún níwájú rẹ. ‘Ó bẹ̀bẹ̀ pé, mú sùúrù fún mi, èmi yóò sì san gbogbo rẹ̀ fún ọ.’
Read full chapter
Matiu 20:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 20:20
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ẹ̀bẹ̀ ìyá
20 (A)(B) Nígbà náà ni ìyá àwọn ọmọ Sebede bá àwọn ọmọ rẹ̀ wá sọ́dọ̀ Jesu, ó wólẹ̀ lórí eékún rẹ̀, o béèrè fún ojúrere rẹ̀.
Read full chapter
Johanu 9:38
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 9:38
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
38 (A)Ó sì wí pé, “Olúwa, mo gbàgbọ́,” ó sì wólẹ̀ fún un.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.