Font Size
Eksodu 22:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Eksodu 22:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 (A)“Ẹnikẹ́ni ti ó bá bá ẹranko lòpọ̀ ní a ó pa.
Read full chapter
Lefitiku 20:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 20:15
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
15 (A)“ ‘Bí ọkùnrin kan bá bá ẹranko lòpọ̀, ẹ gbọdọ̀ pa ọkùnrin náà àti ẹranko náà.
Read full chapter
Lefitiku 20:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 20:16
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
16 “ ‘Bí obìnrin kan bá súnmọ́ ẹranko tí ó sì bá a lòpọ̀ obìnrin náà àti ẹranko náà ni kí ẹ pa: ẹ̀jẹ̀ wọn yóò sì wà lórí ara wọn.
Read full chapter
Deuteronomi 27:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Deuteronomi 27:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
21 (A)“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú ẹranko.”
Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.