Font Size
1 Kọrinti 16:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 16:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 (A)Ǹjẹ́ bí Timotiu bá dé, ẹ jẹ́ kí ó wà lọ́dọ̀ yín láìbẹ̀rù: nítorí òun ń ṣé iṣẹ́ Olúwa, bí èmi pẹ̀lú ti ń ṣe.
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 16:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 16:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Timotiu darapọ̀ mọ́ Paulu àti Sila
16 Ó sì wá sí Dabe àti Lysra: sí kíyèsi i, ọmọ-ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀, tí a ń pè ní Timotiu, ọmọ obìnrin kan tí í ṣe Júù, tí ó gbàgbọ́; ṣùgbọ́n Giriki ní baba rẹ̀.
Read full chapter
1 Kọrinti 7:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 7:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ọ̀rọ̀ nípa ipò ti a wa
17 (A)Ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí olúkúlùkù máa gbé ìgbé ayé tí Ọlọ́run ń fẹ́ yín fún, àti nínú èyí tí Olúwa pè é sí. Ìlànà àti òfin mi fún gbogbo ìjọ ni èyí.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.