Font Size
Romu 1:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 1:5
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
5 (A)Láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwa rí oore-ọ̀fẹ́ àti jíjẹ́ aposteli gbà, fún ìgbọ́ràn ìgbàgbọ́ láàrín gbogbo orílẹ̀-èdè, nítorí orúkọ rẹ̀.
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 15:12
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 15:12
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
12 Gbogbo àjọ sí dákẹ́, wọ́n sì fi etí sí Barnaba àti Paulu, tí wọn ń ròyìn iṣẹ́ ìyanu àti iṣẹ́ ààmì tí Ọlọ́run tí ti ọwọ́ wọn ṣe láàrín àwọn aláìkọlà.
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 21:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 21:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 Nígbà tí ó sì kí wọn tan, ó ròyìn lẹ́sẹẹsẹ ohun gbogbo tí Ọlọ́run ṣe láàrín àwọn aláìkọlà nípa iṣẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.